Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 9:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí náà bá kígbe, ó mú kí gìrì ki ọmọ náà ní akọ, ó sì jáde. Ọmọ náà wá dàbí ẹni tí ó kú, tóbẹ́ẹ̀ tí ọpọlọpọ ninu àwọn eniyan náà ń sọ pé ó ti kú.

Ka pipe ipin Maku 9

Wo Maku 9:26 ni o tọ