Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ mẹfa, Jesu mú Peteru ati Jakọbu ati Johanu lọ sí orí òkè gíga kan, àwọn mẹta yìí nìkan ni ó mú lọ. Ìrísí rẹ̀ bá yipada lójú wọn.

Ka pipe ipin Maku 9

Wo Maku 9:2 ni o tọ