Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá wọn lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, Elija ni ó níláti kọ́ dé láti mú ohun gbogbo bọ̀ sípò.” Ó wá bi wọ́n pé, “Báwo ni a ti ṣe kọ nípa Ọmọ-Eniyan pé ó níláti jìyà pupọ, kí a sì fi àbùkù kàn án?”

Ka pipe ipin Maku 9

Wo Maku 9:12 ni o tọ