Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dé Bẹtisaida. Àwọn ẹnìkan mú afọ́jú kan wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n ń bẹ̀ ẹ́ pé kí ó fọwọ́ kàn án.

Ka pipe ipin Maku 8

Wo Maku 8:22 ni o tọ