Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu mọ ohun tí wọn ń sọ, ó bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ̀ ń sọ láàrin ara yín pé nítorí ẹ kò ní burẹdi lọ́wọ́ ni? Ẹ kò ì tíì mọ̀ sibẹ, tabi òye kò ì tíì ye yín? Àṣé ọkàn yín le tóbẹ́ẹ̀?

Ka pipe ipin Maku 8

Wo Maku 8:17 ni o tọ