Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún wọn pé, “Òtítọ́ ni Aisaya sọ ní àtijọ́ nípa ẹ̀yin àgàbàgebè, tí ó sì kọ ọ́ báyìí pé,‘Ọlọrun wí pé: Ẹnu ni àwọn eniyan wọnyi fi ń yẹ́ mi sí,ṣugbọn ọkàn wọn jìnnà sí mi,

Ka pipe ipin Maku 7

Wo Maku 7:6 ni o tọ