Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ohun kan láti òde wá tí ó wọ inú eniyan lọ tí ó lè sọ ọ́ di aláìmọ́. Ṣugbọn àwọn ohun tí ó ń jáde láti inú eniyan ni ó ń sọ ọ́ di aláìmọ́. [

Ka pipe ipin Maku 7

Wo Maku 7:15 ni o tọ