Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pàṣẹ fún wọn pé kí wọn má mú ohunkohun lọ́wọ́ ní ọ̀nà àjò náà àfi ọ̀pá nìkan. Wọn kò gbọdọ̀ mú oúnjẹ, tabi igbá báárà lọ́wọ́, tabi kí wọn fi owó sinu àpò wọn.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:8 ni o tọ