Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 6:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rí i pé pẹlu ipá ni wọ́n fi ń wa ọkọ̀, nítorí afẹ́fẹ́ ṣọwọ́ òdì sí wọn. Ó tó bí agogo mẹta òru kí Jesu tó máa lọ sọ́dọ̀ wọn. Ó ń rìn lórí omi, ó fẹ́ kọjá lára wọn.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:48 ni o tọ