Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí gbẹ́nàgbẹ́nà ni, ọmọ Maria, arakunrin Jakọbu, ati Juda, ati Simoni? Ṣebí àwọn arabinrin rẹ̀ nìwọ̀nyí lọ́dọ̀ wa yìí?” Wọ́n sì kọ̀ ọ́.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:3 ni o tọ