Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 4:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún bèèrè pé, “Báwo ni à bá ṣe ṣe àlàyé ìjọba Ọlọrun, tabi òwe wo ni à bá fi ṣe àkàwé rẹ̀?”

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:30 ni o tọ