Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn dàbí irúgbìn tí a fún sórí ilẹ̀ rere. Àwọn yìí ni ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tí wọ́n gbà á, tí wọ́n sì so èso, òmíràn ọgbọọgbọn, òmíràn ọgọọgọta, òmíran ọgọọgọrun-un.”

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:20 ni o tọ