Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nítorí tí wọn kò ní gbòǹgbò ninu ara wọn, àkókò díẹ̀ ni ọ̀rọ̀ náà gbé ninu wọn. Nígbà tí ìyọnu tabi inúnibíni bá dé nítorí ọ̀rọ̀ náà lẹsẹkẹsẹ wọn á kùnà.

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:17 ni o tọ