Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn wọnyi ni ti ẹ̀bá ọ̀nà, níbi tí a fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ náà sí: àwọn tí ó jẹ́ pé, lẹsẹkẹsẹ tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, Satani wá, ó mú ọ̀rọ̀ tí a ti fún sinu ọkàn wọn lọ.

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:15 ni o tọ