Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ku òun nìkan, àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀ ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila bèèrè ìtumọ̀ àwọn òwe tí ó fi ń sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Maku 4

Wo Maku 4:10 ni o tọ