Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wò yíká pẹlu ibinu, inú rẹ̀ sì bàjẹ́ nítorí pé ọkàn wọn le. Ó wá wí fún ọkunrin náà pé, “Na ọwọ́ rẹ.” Ó bá nà án. Ọwọ́ rẹ̀ sì bọ́ sípò.

Ka pipe ipin Maku 3

Wo Maku 3:5 ni o tọ