Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 3:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá ìyá rẹ̀ ati àwọn arakunrin rẹ̀ wá, wọ́n dúró lóde, wọ́n bá ranṣẹ pè é.

Ka pipe ipin Maku 3

Wo Maku 3:31 ni o tọ