Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Èwo ni ó rọrùn jù: Láti wí fún arọ náà pé, ‘A dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́,’ tabi láti wí pé, ‘Dìde, gbé ibùsùn rẹ, kí o máa rìn?’

Ka pipe ipin Maku 2

Wo Maku 2:9 ni o tọ