Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kò sí ẹni tíí fi ìrépé asọ titun tí kò ì tíì wọ omi rí lẹ ògbólógbòó ẹ̀wù. Tí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀, aṣọ titun náà yóo súnkì lára ẹ̀wù náà, yóo wá tún fà á ya ju ti àkọ́kọ́ lọ.

Ka pipe ipin Maku 2

Wo Maku 2:21 ni o tọ