Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jesu ti jókòó ní ilé Lefi, ọpọlọpọ àwọn agbowó-odè ati àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ń bá Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ jẹun, nítorí wọ́n pọ̀ tí wọn ń tẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Maku 2

Wo Maku 2:15 ni o tọ