Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 16:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jáde, aré ni wọ́n sá kúrò ní ibojì náà, nítorí ńṣe ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí gbọ̀n pẹ̀pẹ̀, tí wọn ń dààmú. Wọn kò sọ ohunkohun fún ẹnikẹ́ni, nítorí ẹ̀rù ń bà wọ́n.[

Ka pipe ipin Maku 16

Wo Maku 16:8 ni o tọ