Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó wí fún wọn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ṣé Jesu ará Nasarẹti tí a kàn mọ́ agbelebu ni ẹ̀ ń wá? Ó ti jí dìde. Kò sí níhìn-ín. Ẹ wò ó! Ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí nìyí.

Ka pipe ipin Maku 16

Wo Maku 16:6 ni o tọ