Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 16:3-4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bá ara wọn ṣàròyé pé, “Ta ni yóo bá wa yí òkúta kúrò ní ẹnu ibojì?” Bí wọ́n ti gbé ojú sókè, wọ́n rí i pé ẹnìkan ti yí òkúta náà kúrò, bẹ́ẹ̀ ni òkúta ọ̀hún sì tóbi gan-an.

Ka pipe ipin Maku 16

Wo Maku 16:3-4 ni o tọ