Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n ti fi ṣe ẹlẹ́yà tán, wọ́n bọ́ aṣọ àlàárì kúrò ní ara rẹ̀, wọ́n fi aṣọ tirẹ̀ wọ̀ ọ́, wọ́n bá fà á jáde láti lọ kàn án mọ́ agbelebu.

Ka pipe ipin Maku 15

Wo Maku 15:20 ni o tọ