Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 14:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó fi í fún àwọn ọ̀tá ti fi àmì fún wọn. Ó ní, “Ẹni tí mo bá kí, tí mo fi ẹnu kàn ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ ni ọkunrin náà. Ẹ mú un, kí ẹ fà á lọ, ẹ má jẹ́ kí ó bọ́.”

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:44 ni o tọ