Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “O rí ilé yìí bí ó ti tóbi tó? Kò ní sí òkúta kan lórí ekeji níhìn-ín tí a kò ní wó lulẹ̀.”

Ka pipe ipin Maku 13

Wo Maku 13:2 ni o tọ