Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 12:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Amòfin kan lọ sí ọ̀dọ̀ Jesu, ó gbọ́ bí wọn tí ń fi ọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀, ó wòye pé Jesu dá wọn lóhùn dáradára. Ó bá bèèrè pé, “Èwo ni ó ṣe pataki jùlọ ninu gbogbo òfin?”

Ka pipe ipin Maku 12

Wo Maku 12:28 ni o tọ