Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 12:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ti pé a óo jí àwọn òkú dìde tabi a kò ní jí wọn, ẹ kò ì tíì kà ninu Ìwé Mose, níbi ìtàn ìgbẹ́ tí iná ń jó, bí Ọlọrun ti wí fún Mose pé, ‘Èmi ni Ọlọrun Abrahamu ati Ọlọrun Isaaki ati Ọlọrun Jakọbu?’

Ka pipe ipin Maku 12

Wo Maku 12:26 ni o tọ