Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí abúlé tí ẹ̀ ń wò ní ọ̀kánkán yìí, bí ẹ bá ti wọ inú rẹ̀, ẹ óo rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí ẹnikẹ́ni kò gùn rí, tí wọ́n so mọ́ èèkàn, ẹ tú u, kí ẹ fà á wá.

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:2 ni o tọ