Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 11:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin gbọ́, wọ́n ń wá ọ̀nà tí wọn yóo fi pa á. Ṣugbọn wọ́n bẹ̀rù rẹ̀, nítorí ìyàlẹ́nu ni ẹ̀kọ́ rẹ̀ jẹ́ fún gbogbo eniyan.

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:18 ni o tọ