Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé Jerusalẹmu, Jesu wọ àgbàlá Tẹmpili lọ, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí lé àwọn tí wọn ń tà ati àwọn tí wọn ń rà jáde. Ó ti tabili àwọn onípàṣípààrọ̀ owó ṣubú, ó da ìsọ̀ àwọn tí ń ta ẹyẹlé rú.

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:15 ni o tọ