Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rí igi ọ̀pọ̀tọ́ kan tí ó ní ewé lókèèrè, ó bá lọ wò ó bí yóo rí èso lórí rẹ̀. Nígbà tí ó dé ìdí rẹ̀ kò rí ohunkohun àfi ewé, nítorí kò ì tíì tó àkókò èso.

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:13 ni o tọ