Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu jáde, bí ó ti ń lọ lọ́nà, ọkunrin kan sáré tọ̀ ọ́ lọ, ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó bi í pé, “Olùkọ́ni rere, kí ni kí n ṣe kí n lè jogún ìyè ainipẹkun?”

Ka pipe ipin Maku 10

Wo Maku 10:17 ni o tọ