Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Báyìí ni Johanu bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìrìbọmi ninu aṣálẹ̀, tí ó ń waasu pé kí àwọn eniyan ronupiwada, kí wọ́n ṣe ìrìbọmi, kí Ọlọrun lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wọ́n.

Ka pipe ipin Maku 1

Wo Maku 1:4 ni o tọ