Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 1:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ìwòsàn fún ọpọlọpọ àwọn tí ó ní oríṣìíríṣìí àìsàn, ó tún lé ẹ̀mí èṣù jáde. Kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí èṣù náà sọ̀rọ̀, nítorí wọ́n mọ ẹni tí ó jẹ́.

Ka pipe ipin Maku 1

Wo Maku 1:34 ni o tọ