Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 1:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, tí oòrùn wọ̀, àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí gbé gbogbo àwọn tí ara wọn kò dá ati àwọn tí wọ́n ní ẹ̀mí èṣù wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Maku 1

Wo Maku 1:32 ni o tọ