Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí ni ó pa tàwa-tìrẹ pọ̀, Jesu ará Nasarẹti? Ṣé o dé láti pa wá run ni? Mo mọ ẹni tí o jẹ́. Ẹni Mímọ́ Ọlọrun ni ọ́.”

Ka pipe ipin Maku 1

Wo Maku 1:24 ni o tọ