Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti rìn siwaju díẹ̀ sí i, ó rí Jakọbu ọmọ Sebede ati Johanu arakunrin rẹ̀ ninu ọkọ̀, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe.

Ka pipe ipin Maku 1

Wo Maku 1:19 ni o tọ