Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 8:42 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ọmọdebinrin rẹ̀ kan ṣoṣo tí ó ní ń kú lọ. Ọmọ yìí tó ọmọ ọdún mejila.Bí Jesu ti ń lọ àwọn eniyan ń bì lù ú níhìn-ín lọ́hùn-ún.

Ka pipe ipin Luku 8

Wo Luku 8:42 ni o tọ