Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 8:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá bi wọ́n pé, “Igbagbọ yín dà?”Pẹlu ìbẹ̀rù ati ìyanu, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bá ara wọn sọ pé, “Ta nì yìí? Ó pàṣẹ fún afẹ́fẹ́ ati ìgbì omi, wọ́n sì ń gbọ́ràn sí i lẹ́nu!”

Ka pipe ipin Luku 8

Wo Luku 8:25 ni o tọ