Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ̀yin ni a fi fún láti mọ àṣírí ìjọba Ọlọrun, ṣugbọn fún àwọn yòókù, bí òwe bí òwe ni, pé wọn yóo máa wo nǹkan ṣugbọn wọn kò ní mọ ohun tí wọn rí, wọn yóo máa gbọ́ràn ṣugbọn òye ohun tí wọn gbọ́ kò ní yé wọn.

Ka pipe ipin Luku 8

Wo Luku 8:10 ni o tọ