Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹnu yà á. Ó bá yipada sí àwọn eniyan tí ó ń tẹ̀lé e, ó ní, “Mò ń sọ fun yín, n kò rí irú igbagbọ báyìí ní Israẹli pàápàá!”

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:9 ni o tọ