Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan gbọ́, tí ó fi mọ́ àwọn agbowó-odè pàápàá, wọ́n fi ìyìn fún Ọlọrun, wọ́n lọ ṣe ìrìbọmi gẹ́gẹ́ bí ètò ìrìbọmi Johanu.

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:29 ni o tọ