Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn oníṣẹ́ Johanu lọ tán, Jesu bẹ̀rẹ̀ sí sọ ọ̀rọ̀ nípa Johanu fún àwọn eniyan. Ó ní, “Kí ni ẹ jáde lọ wò ní aṣálẹ̀? Igi légbélégbé tí afẹ́fẹ́ ń tì sọ́tùn-ún, ati sósì ni bí?

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:24 ni o tọ