Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dá wọn lóhùn pé, “Ẹ lọ sọ ohun tí ẹ rí ati ohun tí ẹ gbọ́ fún Johanu: àwọn afọ́jú ń ríran; àwọn arọ ń rìn, ara àwọn adẹ́tẹ̀ ń di mímọ́; àwọn adití ń gbọ́ràn, à ń jí àwọn òkú dìde; à ń waasu ìyìn rere fún àwọn talaka.

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:22 ni o tọ