Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọkunrin náà dé ọ̀dọ̀ Jesu, wọ́n ní, “Johanu Onítẹ̀bọmi ni ó rán wa sí ọ láti bi ọ́ pé, ‘Ṣé ìwọ ni ẹni tí ń bọ̀ ni, tabi kí á máa retí ẹlòmíràn?’ ”

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:20 ni o tọ