Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó ti mọ ohun tí wọn ń rò ní ọkàn wọn. Ó sọ fún ọkunrin náà tí ọwọ́ rẹ̀ rọ pé, “Dìde kí o dúró ní ààrin.” Ọkunrin náà bá dìde dúró.

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:8 ni o tọ