Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 6:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wá tún pa òwe yìí fún wọn. Ó ní, “Afọ́jú kò lè fi ọ̀nà han afọ́jú. Bí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀, inú kòtò ni àwọn mejeeji yóo bá ara wọn.

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:39 ni o tọ