Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ayọ̀ ń bẹ fun yín nígbà tí àwọn eniyan bá kórìíra yín, tí wọ́n bá le yín ní ìlú bí arúfin, tí wọ́n bá kẹ́gàn yín, tí wọ́n bá fi orúkọ yín pe ibi, nítorí Ọmọ-Eniyan.

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:22 ni o tọ