Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní Ọjọ́ Ìsinmi kan, bí Jesu ti ń la oko ọkà kan kọjá, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí já ọkà, wọ́n ń fi ọwọ́ ra á, wọ́n bá ń jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Luku 6

Wo Luku 6:1 ni o tọ